Ìròyìn ọ̀tun

Ìròyìn ọ̀tun Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Ìròyìn ọ̀tun, Grocers, Yoruba dun un ka, Otta.

Bí Ọ̀gágun Ibrahim Bàdàmọ́sí Bàbáńgídá ṣe já ìjọba gbà mọ́ Ọ̀gágun Bùhárí lọ́wọ́ jẹ́ kàyéfì fún gbogbo èèyàn. Kódà Bùhár...
14/03/2026

Bí Ọ̀gágun Ibrahim Bàdàmọ́sí Bàbáńgídá ṣe já ìjọba gbà mọ́ Ọ̀gágun Bùhárí lọ́wọ́ jẹ́ kàyéfì fún gbogbo èèyàn. Kódà Bùhárí fúnra rẹ̀ kò gbà pé IBB lè hu irú ìwà yìí.

Inú jìn!

Bí ẹ ò bá gbàgbé, Èèkàn ni Ọ̀gágun Ibrahim Bàdàmọ́sí Bàbáńgídá jẹ́ nínú ìjọba GMB, òun ni ọ̀gá àwọn sójà tí ó sì tún wà lára ìgbìmọ̀ asèjọba.

Ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 1985 tí Bàbáńgídá kéde ara rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí adarí ìjọba Ológun tuntun ló ti fi Bùhárí sí àhámọ́. Àhámọ́ yìí ni Ọ̀gágun Bùhárí wà títí di ọdún 1988.

Bùhárí kúrò ní àhámọ́ tán ló bá kọ ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀. Lóòótọ́ Ajagunfẹ̀yìtì Bùhárí kò ṣàlàyé ìdí tí ó fi kọ́ ìyàwó tó bí ọmọ márùn-ún fún un sílẹ̀ àmọ́ ohun tí àwọn èèyàn ń sọ ni pé Sàfínátù kò tẹ̀lé àsẹ ọkọ rẹ̀. Wọ́n ní Sàfínátù gba nǹkan ìrànwọ́ lọ́wọ́ ìjọba tó yẹ ọkọ rẹ̀ ní sáà nígbà tí ọkọ wà ní àtìmọ́lé. Lẹ́yìn ìkọ̀sílẹ̀ yìí ni Ajagunfẹ̀yìtì ṣẹ̀ṣẹ̀ fẹ́ Aisha gẹ́gẹ́ bí ìyàwó tuntun

Hmmmm! Ipò agbára!

Títí tí Bùhárí fi wọlẹ̀ sùn, mi ò rò pé ó fi orí jìn Bàbáńgídá lórí ẹ̀sùn Ìdìtẹ̀gbàjọba ọdún 1985 yìí.

Ìgbà tí Bùhárí bínú sí IBB, kí wá ni kí Alhaji Usman Sheu Sàgàrí tí Bùhárí náà yẹ̀ ní sáà ṣe?

Ìwà ọ̀dàlẹ̀ ni wọ́n fi pinlẹ̀ òṣèlú láti ọjọ́ tí aláyé ti dáyé....

🚶🚶🚶🚶

21/02/2026
The Hidden Struggles of Journalists: Misunderstood by Those Closest to ThemJournalism is a noble profession. Journalists...
21/02/2026

The Hidden Struggles of Journalists: Misunderstood by Those Closest to Them
Journalism is a noble profession. Journalists inform society, shape public opinion, and give voice to the voiceless. Yet, behind the camera, the microphone, and the printed headlines lies a silent struggle that many people do not see.
One of the biggest challenges journalists face does not come from the public or the government — it often comes from their own families, friends, and relatives.
Because journalists appear frequently on social media, television, radio, and news platforms, many people assume they are wealthy. They see them dressed neatly, speaking confidently, traveling to different cities or even countries, and interviewing important personalities. From the outside, it looks like a life of glamour and financial comfort.
But this assumption is often far from reality.
Families and friends sometimes believe that because people listen to them, read their stories, and follow them online, they must be making a lot of money. When journalists cannot meet financial expectations or constant requests for assistance, they are labeled as stingy or selfish. Some are even mocked or criticized for “pretending” to be successful.
What many do not understand is that looking neat and professional is not a sign of wealth — it is a requirement of the job. A journalist must dress well to gain credibility and respect. It is part of the professional image. Similarly, traveling from one state or country to another is often work-related and sponsored by employers or organizations. It does not automatically mean personal wealth.
In reality, many journalists work under pressure, meet tight deadlines, and sometimes earn modest salaries. They invest in transportation, communication tools, research, and personal development — all to deliver accurate and timely information to the public.
The emotional burden of being misunderstood by loved ones can be heavier than the professional stress itself. Instead of receiving encouragement, some journalists face jealousy, mockery, and unrealistic expectations.
Society must begin to understand that visibility is not the same as wealth. Popularity is not equal to prosperity. Professional appearance does not mean financial abundance.
Journalists deserve appreciation, not suspicion. They deserve support, not envy. Behind every news story is a hardworking individual striving to inform and educate society — often at personal sacrifice.ABDULAZEEZ olaniyi ABDULRAZAQ Alabi @ Cotainer Media. RAMADAN KAREEM!!! ALLAH AKRAM!

19/02/2026

Ramadan kareem! ALLAH AKRAM!

15/09/2025

Address

Yoruba Dun Un Ka
Otta
234

Telephone

+2348032384094

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ìròyìn ọ̀tun posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Ìròyìn ọ̀tun:

Share

Category