AinnA

AinnA Aina Awada

People assistance on this please 🙏🙏🙏
30/06/2025

People assistance on this please 🙏🙏🙏

Old friend
29/06/2025

Old friend

Bought
29/06/2025

Bought

To eat
29/06/2025

To eat

At home
29/06/2025

At home

Arrived Back today
29/06/2025

Arrived Back today

IGI ORO 5_______________________________________________Hmmmmmm won sin Ibidun looto sugbon won o sin sinu Ile,iya oko r...
29/06/2025

IGI ORO 5

_______________________________________________

Hmmmmmm won sin Ibidun looto sugbon won o sin sinu Ile,iya oko re so fun Omo re pe ki won o lo ra Ile fun ni Tori ki o ma ba maa seru ba awon Omo re atipe se Olamilekan mope awon Omo re si kere ki won o ma lo maa sunkun ni ibi saare iya won,oko gba si iya re lenu,won gbe Ibidun lo si ile ajeji lo sin,leyin ojo keta won se adura fun oku,olukaluku gba ona ile re lo o ku iya ati Omo re ati Omo ti Ibidun bimo le.

Katowi kato fo gbogbo eru mama ti Kun Inu Ile,mama ti fi ogbogbon ko eru won wa SI Inu Ile Omo won,won si nse ise iya fun Omo ti Ibidun fi sile.Nigbati o pe ojo mejilelogun ti Ibidun ku ni obinrin kan bawa Olamilekan wa PE oun wa ki ku asehinde Ibidun,omobinrin naa je Okan lara awon omoge ti Olamilekan ti fe ni igba omoge,Inu mama dun pe olohunseun,mama gba omobinrin naa tayotayo,mama si ro pe ko ma lo si Ile lojo yen niwon igba ti omobinrin naa ni oun o ti Loko kankan.

Omobinrin naa sun ti Olamilekan mojumo koda o lo OSE kan gbako ki o to lo,bee ni Inu mama ndun pe Iyawo miran tide fun Omo awon laitipe ogoji ojo ti Ibidun ku.HMMMM GBOGBO AWA ABIYAMO PATA A NII DA ERU WA SI IRONA OOOO 🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏

Bi omobinrin yii se nwa niyi t**i o fi pe ogoji ojo,ojo to pe ogoji ojo geerege to Ibidun ku ni isele kayeefi bere si sele ninu ile won oooo,sadede ni won ngbo ekun loru ninu yara igbalejo won,ti Eni naa nmi amikan,ti ekun re si rinle gidi,mama sare jade oun ati Lekan jo pade sugbon won o ri enikeni bee ni ekun o si dawo duro mo nbo naa ko ma gun ju tori ati ka........

Just for youOrder now Food NetworkFoodies & Spice
31/05/2025

Just for you

Order now Food Network
Foodies & Spice

Your food available to eat
14/07/2024

Your food available to eat

Happy Saturday
08/06/2024

Happy Saturday

Address

Oro
Abuja

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when AinnA posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share

Category