Asiri nipa irawo eda ati asiri ewe ati egbo

Asiri nipa irawo eda ati asiri ewe ati egbo Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Asiri nipa irawo eda ati asiri ewe ati egbo, Grocers, Ola oluwa Street opposite amuloko, Ibadan.

05/06/2024

Bere fun Ogun toba fe

19/04/2024

STROKE (ROPAROSE)
ALUBOSA AYU,AO GE SINU IGO,AO WA FI OMI IGBIN SI,AO MA MU
NISIBI MEJI FUNAGBALAGBA,SIBIKAN FUN OMODE
LOJOJUMO,OLOHUN KONI FI STROKE BA WA JA OO.

19/04/2024

OSE_EYONU_OMO_ARAIYE

ỌRỌ AGOGO ,
ẸRÚ ALAMO ,
ODIDI ATAARE KÀN ,
ÈPO OBO ,
EWÉ ÀLÚPÀYÍDÀ ,
EWEPATANMO,
ỌGÁ GBÍGBÉ MẸTA.
AO GUN PAPỌ DAADA PẸLU ỌSẸ DÚDÚ , ÀWA FÍ OMINAGBON POPO , AOKO SÍNÚ ÌGBA AGBỌN , INÚ ÌGBA AGBỌN YÍ LAOTI MAN BU ỌSẸ YI WẸ .

Lati mo nipa irowo ti hon shey bami soro LoriCall: 07013822057Whatsapp: 09061932032
19/04/2024

Lati mo nipa irowo ti hon shey bami soro Lori
Call: 07013822057
Whatsapp: 09061932032

OSHOLE AJE FUNFUN OGUNDABEDE BERE LATI 29 YEARS TORI ENI TOBA SE ISE YI KONI LOJU OGBON ODUN LO LAIYE 75 YEARS SUGBON YI...
19/04/2024

OSHOLE AJE FUNFUN OGUNDABEDE BERE LATI 29 YEARS TORI ENI TOBA SE ISE YI KONI LOJU OGBON ODUN LO LAIYE 75 YEARS SUGBON YIO NI IYALAYA AGBAKO OWO ISE YI GBOGBO IRE AJE OWO NI GBOGBO ORIGUN MERERIN AGBAYE NI ISE YIO MA GBEWA ENIYAN TOBA SE ISE YI YIO NI OWO NLA GBOGBO IRANDIRAN RE KO TUN TOSI MO LAYE SUGBON OGBON ODUN NI YIO LO LAIYE 30 YEARS
ISE NAA REE

1 eyele FUNFUN nla kan
Lekeleke funfun nla kan
Atelewo otun ogundabede to njale dada
Atelewo osi inaki
ODIDI atare 201
Orogbo 201
Obi abata 201
Ewe aje 201
Ewe kuje kuje 201
Ewe ABAMODA 201
Ewe ella 201
Ijapa nla meta
Igba nla kan tio tobi dada
Agbo funfun nla kan
Opa a*o funfun meji

Sise ise yi ree o ao gbe atelewo otun ogundabede tele inu igba toma siju soke aowa da atelewo osi inaki bo mole aowa gbe eyele funfun si apa otun lekeleke funfun si apa osi aowa to gbogbo eroja toku si round aowa fi awon ewe tutu yen bo mole aowa gbe sinu a*o funfun opa meji aowa we gbogbo ara re ni owu funfun ti ao ni ri igba yen mo odi aje ogunguniso aowa lo rimo iledu ni arin ogede fun ojo mesan leyin ojo kesan aolo wu jade aowa gbe sinu agbada nla kan odi jijo ago mejila oru ni jijo ise yi ago mejila oru lama lo ri mole ao fi epo pupa pero aro ijogun ise yi toba jotan ao lo kuna dada aowa po mo ose egberun kan abo pelu eje agbo funfun yen lai fi omi si rara ko ose yi sinu igba aje nla kan igba onikoko aowa gbe si igun yara wa eran agbo yen ao fi nkan inu re se etutu fun awon agba ni orita meta ao fi eran toku se sara fun awon oni bara

Lilo ise yi aoma we ose yi ni ojo aje ojo aje Monday Monday nikan ti a ba we ose yi larin osu kan pere ao di olowo nla olola nla ao di olowo olola larin egbe wa ao di olowo gidi ao kuro ninu osi ati iya lowo airije airimu ao si gbe nkan gidi se laye kole nla ra motor gidi gbe nkan rere se sugbon OGBON ODUN NI YIO LO LAIYE 30 YEARS pere odamiloju gidi gan ise baba baba mi ni tia ma se fun awon eniyan LORISIRISI ni Nigeria loke okun

CALL 07013822057
WHATSAPP 09061932032

Address

Ola Oluwa Street Opposite Amuloko
Ibadan

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Asiri nipa irawo eda ati asiri ewe ati egbo posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share

Category