18/07/2023
Ifasuyi Omotoso Kazeem, tíí ṣe Olóòlù nílẹ̀ Ibadan lọ́dún 2020, ti ṣàlàyé lórí ọ̀pọ̀ ewu tó wà nínú kí Olubadan tàbí ìjọba pàṣẹ pé kí Egúngún máṣe jáde ní ọdún kan, tó sì ní òun ti rí ibi tí eléégún kan ti pàdánù ọmọ méjì nígbà tí ìjọba ní kó má jáde. Àkójọpọ̀ àwọn aburú tí Olóòlù tọ́ka sí rèé bí wọn bá ti egúngún mọ́lé láàrin ọdún kan: