Ogun awon baba nla tested and confirm todaju

Ogun awon baba nla tested and confirm todaju Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Ogun awon baba nla tested and confirm todaju, Grocers, Ogbomoso.

17/06/2023

Fun ona abayo fun awon eniyan eledumare oba orun chat mi or follow my page
Oniruru ona ti o ba fe.
1. Isegun Ogun ojo pipe
2. Asiri ona abayo fun gbogbo ona
3 eyonu Owo ati omiran
4 isegun iba pelu kokora Ara.
5. Ituwo aye ati imule agba.
6. Isegun amubo pelu ibalobo oju run ati ojeoju orun
7.Isewiwa
8. Isegun asedanu
9. Isoye omo Ile iwe ati ekose

10. Afose abi awise adura awon woli Ati bebelo.

17/06/2023

Ogun kokoro pelu isegun , eyonu ni oriruru ona today confirm.

Elore: ewe irawo Ile
ewe bara tutu
Ose eyikeyi
Lilore: ao lo ewe irawo Ile ati ewe bara papo mo ose tio bawuwa papo.

Agbore: EWA Omi gbigbo na se ewe mejeji EWA dasi nu ike kan o badiminu pelu ase olorun. Fi ifa eji ogbe paofore ' '
' '
' '
' '
Ridajupe ofi idupere fun eledumare oba orun
A je ooo.

09/06/2023

Fun awise adura
Lopa epolapalapa bidie kidasi Inu ike kan pelu kanun ati bomi sinure odaju biku ase awon tisin ni kese ti gbani leleyi sugban odaju. Kiran ti lati dope lowo eledumare aseda.

Anything that u when asking me eledumare Mase chat me up on my base username if whant something.

08/06/2023

Ogun Lati re baro fun exam
Elo bamiwa bayiro oun kowe meje SI le
Pelu tandiri kan so WA tibo Inure fun 3 days or 1days, 2days mu eyokan ninu funsise.

31/05/2023

Ogun isegun
A o wa iyepe iwaju iIe pelu omi iwe ti olewetan wamu erupe pelu ifa ejiogbe.

Ofore re; ifa ejiogbe emi lagbaja omolagbaja mobere lati odo eledumare toda orun ohun aye peluse isegun oso,aje, emere at awon ologun Ika woli ni pastors ni emasa segun temi ase ase ase eledumare.

Address

Ogbomoso

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ogun awon baba nla tested and confirm todaju posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share

Category